Lit by Sister Kofo for Siblings and Families 11th January 2014
Ajibola Oba; Omo so'mo; Abitira bi iseso, ojo gbogbo bi eni nsodun. Omo Olowu, Omo Amororo; ikete ni ara yoku, ojulowo epo ni omo Amoro. Ma sun lo ololufe ki o si ma simi. Gbe ori le aya Olugbala re, A fe o, sugbon Jesu fe or ju! Sun re o Adigun omo Olo'fa. "Jibola" "AjibOye!" "Bo-Jibo" "Uncle Jibola" We Love You and Miss You Ever So Much
This candle went out on 12th January 2015.